Ile ẹjọ ni ki Tokẹ Makinwa san miliọnu kan naira fun ọkọ ẹ tẹlẹ

0
82

Dada Ajikanje

Miliọnu kan naira nile-ẹjọ giga kan niluu Eko ni ki gbajumọ sọrọsọrọ nni, Tokẹ Makinwa, san fun ọkọ ẹ tẹlẹ, Maje Ayida, lori pe o ba ọkunrin naa lorukọ jẹ.
Ninu idajọ Adajọ Olukayọde Ogunjọbi, lo ti sọ pe Makinwa gbọdọ yọ ohun to kọ nipa ọkọ ẹ tẹlẹ yii kuro ninu iwe to kọ, to pe akọle ẹ ni “On Becoming”.
O lo gbọdọ ṣatunṣe ọhun lori eyi to ku ti ko ti i ta ninu awọn iwe naa laarin ọgbọnjọ.

via FUN GBIGBA IROYIN WOLE TABI IFISUN TABI IDUPE (EKAN SI WA LORI WHATSAPP) 08162470398

Previous articleAwọn aṣofin Ondo ba mọlẹbi awọn to ku sinu ijamba ọkọ l’Akungba Akoko kẹdun
Next article[Mixtape] DJ Lawazy – “Orbloblo Mix”
Software Developer, Data Analyst, Blogger, Writter, Promoter, Internet Sensational and Spammer ¦ I Building Solutions from West Naija to the World || +2348162470398 (Whatsapp/Telegram)